Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 21:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa Ọlọrun Israeli wi, Kiyesi i, emi nmu iru ibi bayi wá sori Jerusalemu ati Juda, ti ẹnikẹni ti o ba gbọ́ ọ, eti rẹ̀ mejeji yio ho.

2. A. Ọba 21

2. A. Ọba 21:10-16