Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 19:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dẹti rẹ silẹ Oluwa, ki o si gbọ́; ṣi oju rẹ, Oluwa, ki o si wò: ki o si gbọ́ ọ̀rọ Sennakeribu ti o rán lati kẹgàn Ọlọrun alãyè.

2. A. Ọba 19

2. A. Ọba 19:8-20