Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li ọdun kẹrin Hesekiah ọba, ti iṣe ọdun keje Hoṣea ọmọ Ela ọba Israeli, ni Ṣalmaneseri ọba Assiria gòke wá si Samaria, o si dotì i.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:1-17