Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin ọdun mẹta nwọn kó o; ani li ọdun kẹfa Hesekiah, eyini ni ọdun kẹsan Hoṣea ọba Israeli li a kó Samaria.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:2-17