Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 18:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti nwọn kò gbà ohùn Oluwa Ọlọrun wọn gbọ́, ṣugbọn nwọn dà majẹmu rẹ̀, ati ohun gbogbo ti Mose iranṣẹ Oluwa pa li aṣẹ, nwọn kò si fi eti si wọn, bẹ̃ni nwọn kò si ṣe wọn.

2. A. Ọba 18

2. A. Ọba 18:9-14