Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati majẹmu ti mo ti ba nyin dá ni ẹnyin kò gbọdọ gbàgbe; bẹ̃ni ẹnyin kò gbọdọ bẹ̀ru awọn ọlọrun miran.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:37-41