Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati idasilẹ wọnni, ati ilàna wọnni, ati ofin ati aṣẹ ti o ti kọ fun nyin, li ẹnyin o mã kiyesi lati mã ṣe li ọjọ gbogbo; ẹnyin kò si gbọdọ bẹ̀ru awọn ọlọrun miràn.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:33-41