Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 17:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti o yà Israeli kuro ni idile Dafidi; nwọn si fi Jeroboamu ọmọ Nebati jọba: Jeroboamu si tì Israeli kuro lati má tọ̀ Oluwa lẹhin, o si mu wọn ṣẹ̀ ẹ̀ṣẹ nla.

2. A. Ọba 17

2. A. Ọba 17:15-23