Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahasi si rán onṣẹ si ọdọ Tiglat-pileseri ọba Assiria wipe, Iranṣẹ rẹ li emi, ati ọmọ rẹ; gòke wá, ki o si gbà mi lọwọ ọba Siria, ati lọwọ ọba Israeli, ti o dide si mi.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:1-15