Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li akokò na, Resini ọba Siria gbà Elati pada fun Siria, o si lé awọn enia Juda kuro ni Elati: awọn ara Siria si wá si Elati, nwọn si ngbe ibẹ titi di oni yi.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:1-11