Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 14:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiki a kò mu ibi giga wọnni kuro; sibẹ awọn enia nṣe irubọ, nwọn si nsun turari ni ibi giga wọnni.

2. A. Ọba 14

2. A. Ọba 14:1-11