Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si ṣe eyiti o buru li oju Oluwa; on kò lọ kuro ninu gbogbo ẹ̀ṣẹ Jeroboamu ọmọ Nebati, ẹniti o mu Israeli ṣẹ̀: ṣugbọn o rìn ninu wọn.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:6-21