Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọdun kẹtadilogoji Joaṣi ọba Juda, Jehoaṣi ọmọ Jehoahasi bẹ̀rẹ si ijọba lori Israeli ni Samaria, o si jọba li ọdun mẹrindilogun.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:3-13