Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 12:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Josakari ọmọ Simeati ati Jehosabadi ọmọ Ṣomeri, awọn iranṣẹ rẹ̀ pa a, o si kú; nwọn si sìn i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi: Amasiah ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

2. A. Ọba 12

2. A. Ọba 12:11-21