Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 12:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn iranṣẹ rẹ̀ si dide, nwọn si dì rikiṣi, nwọn si pa Joaṣi ni ile Millo, ti o sọ̀kalẹ lọ si Silla.

2. A. Ọba 12

2. A. Ọba 12:15-21