Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si de Samaria, o pa gbogbo awọn ti o kù fun Ahabu ni Samaria, titi o fi run u, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa ti o sọ fun Elijah.

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:16-21