Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si wipe, Ẹ mu wọn lãyè, nwọn si mu wọn lãyè, nwọn si pa wọn nibi iho ile irẹ́run agùtan, ani ọkunrin mejilelogoji, bẹ̃ni kò si kù ẹnikan wọn.

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:6-16