Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jehu pade awọn arakunrin Ahasiah ọba Juda, o si wipe, Tali ẹnyin? Nwọn si dahùn wipe, Awa arakunrin Ahasiah ni; awa si nsọ̀kalẹ lati lọ ikí awọn ọmọ ọba ati awọn ọmọ ayaba.

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:5-20