Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AHABU si ni ãdọrin ọmọ ọkunrin ni Samaria. Jehu si kọwe, o si ranṣẹ si Samaria si awọn olori Jesreeli, si awọn àgbagba, ati si awọn ti ntọ́ awọn ọmọ Ahabu, wipe,

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:1-6