Yorùbá Bibeli

1. Kro 25:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn wọnyi li o wà labẹ ọwọ baba wọn, fun orin ile Oluwa, pẹlu kimbali, psalteri ati duru, fun ìsin ile Ọlọrun: labẹ ọwọ ọba, ni Asafu, Jedutuni, ati Hemani wà.

1. Kro 25

1. Kro 25:1-8