Yorùbá Bibeli

1. Kro 25:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn wọnyi li awọn ọmọ Hemani, woli ọba ninu ọ̀rọ Ọlọrun, lati ma gbé iwo na soke. Ọlọrun si fun Hemani li ọmọkunrin mẹrinla ati ọmọbinrin mẹta.

1. Kro 25

1. Kro 25:1-14