Yorùbá Bibeli

1. Kro 17:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si yan ibi kan fun Israeli awọn enia mi, emi o si gbìn wọn, ki nwọn le má gbe ipò wọn, a kì yio si ṣì wọn mọ; bẹ̃ni ọmọ buburu kì yio yọ wọn lẹnu mọ, bi ti atijọ;

1. Kro 17

1. Kro 17:4-16