Yorùbá Bibeli

1. Kro 17:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi si ti wà pẹlu rẹ ni ibikibi ti iwọ ba lọ, emi si ti ké gbogbo awọn ọta rẹ kuro niwaju rẹ, emi o si ṣe ọ li olorukọ kan, bi orukọ awọn enia nla ti o ti wà li aiye.

1. Kro 17

1. Kro 17:6-17