Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:66 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ kẹjọ o rán awọn enia na lọ: nwọn si sure fun ọba, nwọn si lọ sinu agọ wọn pẹlu ayọ̀ ati inu-didun, nitori gbogbo ore ti Oluwa ti ṣe fun Dafidi, iranṣẹ rẹ̀, ati fun Israeli, enia rẹ̀.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:62-66