Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:65 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li àkoko na, Solomoni papejọ kan, ati gbogbo Israeli pẹlu rẹ̀, ajọ nla-nlã ni, lati iwọ Hamati titi de odò Egipti, niwaju Oluwa Ọlọrun wa, ijọ meje on ijọ meje, ani ijọ mẹrinla.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:61-66