Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti o ti ba iranṣẹ rẹ Dafidi, baba mi pa ohun ti iwọ ti ṣe ileri fun u mọ: iwọ fi ẹnu rẹ sọ pẹlu, o si ti fi ọwọ́ rẹ mu u ṣẹ, gẹgẹ bi o ti ri loni.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:23-34