Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Oluwa Ọlọrun Israeli, kò si Ọlọrun ti o dabi rẹ loke ọrun, tabi ni isalẹ ilẹ, ti ipa majẹmu ati ãnu mọ pẹlu awọn iranṣẹ rẹ ti nfi gbogbo ọkàn wọn rin niwaju rẹ:

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:21-32