Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ọkunrin Israeli si pe ara wọn jọ si ọdọ Solomoni ọba ni ajọ ọdun ni oṣu Etanimu, ti iṣe oṣu keje.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:1-7