Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBANA ni Solomoni papejọ awọn agba Israeli, ati gbogbo awọn olori awọn ẹ̀ya, awọn olori awọn baba awọn ọmọ Israeli, si ọdọ Solomoni ọba ni Jerusalemu, ki nwọn ki o lè gbe apoti-ẹri majẹmu Oluwa wá lati ilu Dafidi, ti iṣe Sioni.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:1-6