Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iwọ o ba si rìn ni ọ̀na mi lati pa aṣẹ ati ofin mi mọ, gẹgẹ bi Dafidi baba rẹ ti rìn, emi o si sún ọjọ rẹ siwaju.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:13-22