Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati eyiti iwọ kò bere, emi o fun ọ pẹlu ati ọrọ̀ ati ọlá: tobẹ̃ ti kì yio si ọkan ninu awọn ọba ti yio dabi rẹ.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:8-21