Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 22:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ọba Israeli kó awọn woli jọ, bi irinwo ọkunrin, o si wi fun wọn pe, Ki emi ki o ha lọ si Ramoti-Gileadi lọ ijagun, tabi ki emi ki o jọwọ rẹ̀? Nwọn si wipe, Goke lọ: nitoriti Oluwa yio fi i le ọba lọwọ.

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:3-16