Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 22:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Israeli si wi fun awọn iranṣẹ rẹ̀ pe, Ẹnyin ha mọ̀ pe, tiwa ni Ramoti-Gileadi, awa si dakẹ, a kò si gbà a kuro lọwọ ọba Siria?

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:1-11