Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 22:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wipe, Tani yio tàn Ahabu, ki o le goke lọ, ki o si le ṣubu ni Ramoti-Gileadi? Ẹnikan si wi bayi, ẹlomiran si sọ miran.

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:15-23