Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 21:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn kò si ẹnikan bi Ahabu ti o tà ara rẹ̀ lati ṣiṣẹ buburu niwaju Oluwa, ẹniti Jesebeli aya rẹ̀ ntì.

1. A. Ọba 21

1. A. Ọba 21:19-29