Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 20:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si kà iye ogun fun ara rẹ gẹgẹ bi ogun ti o ti fọ́, ẹṣin fun ẹṣin, ati kẹkẹ́ fun kẹkẹ́: awa o si ba wọn jà ni pẹ̀tẹlẹ, nitõtọ awa o li agbara jù wọn lọ. O si fi eti si ohùn wọn, o si ṣe bẹ̃.

1. A. Ọba 20

1. A. Ọba 20:20-35