Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nisisiyi, máṣe jẹ ki o ṣe alaijiya, nitori ọlọgbọ́n enia ni iwọ, iwọ si mọ̀ ohun ti iwọ o ṣe si i; ṣugbọn ewú ori rẹ̀ ni ki o mu sọkalẹ pẹlu ẹjẹ sinu isa-okú.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:7-18