Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 2:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si ranṣẹ, o si pe Ṣimei, o si wi fun u pe, Kọ́ ile fun ara rẹ ni Jerusalemu, ki o si ma gbe ibẹ̀, ki o má si ṣe jade lati ibẹ lọ si ibikibi.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:34-45