Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 12:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Baba rẹ sọ àjaga wa di wuwo: njẹ nitorina, ṣe ki ìsin baba rẹ ti o le, ati àjaga rẹ̀ ti o wuwo, ti o fi si wa li ọrùn, ki o fẹrẹ̀ diẹ, awa o si sìn ọ.

1. A. Ọba 12

1. A. Ọba 12:1-13