Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 12:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Rehoboamu si wá si Jerusalemu, o ko gbogbo ile Juda jọ, pẹlu ẹya Benjamini, ọkẹ mẹsan enia ti a yàn, ti nwọn iṣe ologun, lati ba ile Israeli ja, lati mu ijọba na pada bọ̀ sọdọ Rehoboamu, ọmọ Solomoni.

1. A. Ọba 12

1. A. Ọba 12:17-22