Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 12:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe nigbati gbogbo Israeli gbọ́ pe Jeroboamu tun pada bọ̀, ni nwọn ranṣẹ, nwọn si pè e wá si ajọ, nwọn si fi i jọba lori gbogbo Israeli: kò si ẹnikan ti o tọ̀ ile Dafidi lẹhin, bikoṣe kiki ẹya Juda.

1. A. Ọba 12

1. A. Ọba 12:17-25