Yorùbá Bibeli

Esr 8:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. WỌNYI ni awọn olori ninu awọn baba wọn, eyi ti a kọ sinu iwe itan-idile awọn ti o ba mi goke lati Babiloni wá, ni ijọba Artasasta ọba.

2. Ninu awọn ọmọ Finehasi, Gerṣomu: ninu awọn ọmọ Itamari, Danieli: ninu awọn ọmọ Dafidi, Hattuṣi.