Yorùbá Bibeli

Esr 8:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

WỌNYI ni awọn olori ninu awọn baba wọn, eyi ti a kọ sinu iwe itan-idile awọn ti o ba mi goke lati Babiloni wá, ni ijọba Artasasta ọba.

Esr 8

Esr 8:1-2