Yorùbá Bibeli

Esr 2:68 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ninu awọn olori awọn baba, nigbati nwọn de ile Oluwa ti o wà ni Jerusalemu, nwọn si ta ọrẹ atinuwa fun ile Ọlọrun, lati gbe e duro ni ipò rẹ̀.

Esr 2

Esr 2:61-70