Yorùbá Bibeli

Eks 39:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni gbogbo iṣẹ agọ́ ti agọ́ ajọ na pari: awọn ọmọ Israeli si ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti OLUWA palaṣẹ fun Mose, bẹ̃ni nwọn ṣe.

Eks 39

Eks 39:25-42