Yorùbá Bibeli

Eks 33:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si mú agọ́ na, o si pa a lẹhin ibudó, li òkere rére si ibudó; o pè e ni Agọ́ ajọ. O si ṣe, olukuluku ẹniti mbère OLUWA o jade lọ si agọ́ ajọ, ti o wà lẹhin ibudó.

Eks 33

Eks 33:6-9