Yorùbá Bibeli

Eks 30:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

A ko gbọdọ dà a si ara enia, bẹ̃li ẹnyin kò gbọdọ ṣe irú rẹ̀, ni ìwọn pipò rẹ̀: mimọ́ ni, yio si ma ṣe mimọ́ fun nyin.

Eks 30

Eks 30:27-38