Yorùbá Bibeli

Eks 28:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

On o si wà lara Aaroni lati ma fi ṣiṣẹ: a o si ma gbọ́ iró rẹ̀ nigbati o ba wọ̀ ibi mimọ́ lọ niwaju OLUWA, ati nigbati o ba si njade bọ̀, ki o má ba kú.

Eks 28

Eks 28:32-43