Yorùbá Bibeli

Eks 25:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn kerubu na yio si nà iyẹ́-apa wọn si oke, ki nwọn ki o fi iyẹ́-apa wọn bò itẹ́-ãnu na, ki nwọn ki o si kọjusi ara wọn; itẹ́-ãnu na ni ki awọn kerubu na ki o kọjusi.

Eks 25

Eks 25:10-25