Yorùbá Bibeli

Eks 19:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, li owurọ̀ ijọ́ kẹta, ni ãrá ati mànamána wà, ati awọsanma ṣíṣu dùdu lori òke na, ati ohùn ipè na si ndún kikankikan; tobẹ̃ ti gbogbo awọn ti o wà ni ibudó warìri.

Eks 19

Eks 19:13-24